Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Mo gbọ pe awọn agbebọn to pa eeyan to le logoji nile ijọsin Katoliki ilu Owo nipinlẹ Ondo lọdun mẹta sẹyin tun lawọn n pada bọ o.
Ko jẹ jẹ bẹẹ, ao tun ni ribi mọ nilẹ yii.
Agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo, Ayanlade Olusola, sọ fun BBC pe awọn ọtẹlẹmuyẹ ti wa kaakiri Ondo.
Kini ijọba ipinlẹ ọhun wi
Lọ ọ ka iyoku ni bbc.com/yoruba
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Ìgalà fa ìjàmbá fún bàálù, ó tún ṣàkóbá ìrìnàjò òfurufú ní Delta
Ọjọ Abamẹta ni iroyin sọ pe Igala naa jana mọ baaluu lẹnu lasiko to n gbera lati fo
Ọga agba ajọ to n mojuto ibaṣepọ araalu ninu ajọ NCAA Michael Achimugu, sọ pe
Iṣẹlẹ ọhun tun fa akoba fun awọn baalu mii to yẹ ko fo
..................................................................................................
Ajọ to n dena fifini ṣowo ẹru ni Naijiria, NAPTIP ti ko ọmọ Naijiria mejindinlọgọrin wale lati Cote-d' voire.
Ọga agba NAPTIP, Binta Adamu Bello, to tẹwọ gba awọn ọmọbinrin naa ni papakọ ofurufu Murtala l'Eko sọ pe
oloyun ati ọmọ ọwọ n bẹ ninu wọn.